ISE ISIN ONIGBAGBO
Óye
Isé gbogbo Krìstéénì ni láti ní ìwà létòlétò àti ìyára. Kò sí àwáwí fún àìyára lénu isé. Tí ènìyàn bá ma ń wà lénu isé nígbàgbogbo, tí isé kò sì jé síse, ìdí fún èyí ni pé okàn àti èmí kò sí níbi isé náà. Eni tì kò yára, tí kò sì sisé bí ó ti ye kó se é gbudò mò wípé ohun tí kò dára, tí ó sì gbodò ní àtúnse. Ó gbodò pa okàn rè pò, kí ó sì kó bí a ti ń lo àkókò rè ní dáradára láti rí èrè tí ó dára jùlo. Pèlú òye àti ìlànà òpòlopò yóò se isé tí ó pò ní wákàtí márùn-ún ju àwon tí ó lo wákàtí méwàá fún isé béè lo. Àwon tí ó má se isé ilé má a ń se nígbàgbogbo, kìí se ńitorí pé wón ní òpòlopò isé láti se bíkòse pé won kò fi ètò láti dín wákàtí isé won kù. IIO 237.3
Nípa àìníyára àti àìbìkítà tàbí ìwà fòní-dónìí won, won á máa so isé kékeré di púpò. Sùgbón àwon tí ó bá lè borí èyí nípa níní àfojúsùn tí ó pé. Pinnu láti gbé gègé le isé tí a yàn, kí o sì gbìyànjú dáradára láti rí pé isé náà jé isé ní àkókò tí ó tò. Èrè nígbà yìí yóò jé kí owó isé déédéé.—Christ’s Object Lessons, p. 344. IIO 237.4
Isé Olorun ń fé ìgboràn tí ó se kánkán.—The Southern Watchman, Aug. 9, 1904. IIO 237.5
Olorun fé kí àwon olùsìn Rè wà ní inú èmí tí ó yára láti mo ìwúlò ènìyàn, mo isé láti se, ìyára láti sisé tí Olúwa ń yàn fún won.—Testimonies, vol. 9, pp. 123, 124. IIO 238.1
Aápon nínú isé tí Olórun yàn jé ohun tí ó se pàtàkì nínú ìsìn tòótó. Yíyára àti níní èrò isé ní àkókò tí ó tò má a mú gègé tí ó wuyì wá, nígbà tí ìdádúró àti ipa ti má yorí sí ìkùnà àti àbùkù sí Olórun.—Prophets and Kings, p. 676. IIO 238.2