ISE ISIN ONIGBAGBO

235/273

Ìwà Ìsóótó Sí Enìkansoso

Olúwa kóríra ìwà àìbìkítà àti àìní òótó nígbà ìpónjú nínú isé Rè. Gbogbo ayé yóò wo ìran ibi tí ìjà àríyànjiyàn ń lá láti ìmólè àti òkùnkùn yóò jásí. Àwon ènìyàn Olórun súnmólé. Kíni ó lè jé ohun tí ó se pàtàkì, tí ó se pàtàkì sí won jù láti jé olóótó sí Olórun òrun lo? IIO 237.1

Ní gbogbo ìgbà, Olórun ti ní àwon àkoni ní isé tí ó tó, Ó sì ní won báyìí, àwon bí Jóséfù àti Dáníélì, won kò tijù láti pe ara won, àwon ènìyaǹ òrò rè. Ìbùkún òrò Rè ń tèlé isé àwon ènìyan rè, àwon tí a kò lè tì kúrò lónà tí ó tó, eni tí ó ní agbára òrun ó ní yì, kò béèrè pé “tani kò wà nípa ti Olórun?” Àwon tí kò ní ìbèrè lásán sùgbón tí yóò to àwon tí ó setán lo, tí yóò pè wón síta láti fi ìsìn won hàn sí Oba àwon oba àti Olúwa àwon olúwa. Irú àwon ènìyàn béè fi èrò àti ìse won jé omo èhìn sí òfin Olúwa. Fún ìfé rè, wón kú sí ara won. Isé won ni láti gba ìmólè láti inú òrò Olórun, láti jé kí ó tàn sí gbogbo àgbáyé dáadáa, ìtànsán tí kìí kú. Olóótó sí Olórun ni àkomònà won.—Prophets and Kings, p. 148. IIO 237.2