ISE ISIN ONIGBAGBO

234/273

Tokàn-Tokàn

A gbodò ní láti ya àwon ènìyàn Olórun sótò gégébí àwon tó ń sìn tokàn-tokàn, won kìí gba oríyìn kankan fun ara won, ní ìrántí pé pèlú májèmú olówò, wón ti dá ara won láti sin Olórun nìkan soso. IIO 236.1

Àwon okùnrin àti obìnrin tí ó ń sin Olórun tokàn-tokàn, tí ó ti pinnu láti inú okàn won nìkan ni ó lè dúró nínú àkókò tí a wa yí. Kristi jo àwon òlùtèlé ní lópòlopò ìgbà títí yóò fi ku mókànlá àti àwon obìnrin díè láti fi ìfilélè ìjo Olórun sílè. Àwon tí yóò sá séyìn wa nígbà tí ìsòro bá wa láti dojúko, sùgbón tí ìgbà tí ìjo bá ń tàn, won á fò fáyò, korin pèlú ìtara nínú ayò ń lá, sùgbón a ní láti kíyèsí won. Kálébù ni ó dìde bó sí gbangba láti fi ìpilèsè èkó rere tí ó lè subú hàn. Àwon yìí ni kò sọ adun won nù. Ìgbà tì isé ìjo bá lo ní dédé, ni a má rí àwon olùrànlówó tòótó.—Testimonies, vol. 5, p. 130. IIO 236.2

Kò sí eni tí ó lè sàseyorí nínú isé Olórun láìní ìfokànsìn tokàn-tokàn, tí ó sì fi gbogbo ìgbà ń wá ìmò Kristi láìní ìfokànsì ohun ayé. Enití kò bá lè da gbogbo ti owó rè sílè, kò lè jé omo èyìn Kristi tàbí alábàásisé Rè.—The Desire of Ages, p. 273. IIO 236.3

Won kò gbodò dábàá tàbí bá àwon aláìnígbàgbó dòwòpò, nítorí eléyìí yóò dènà fún wa nínú isé tí Olórun gbé fún won.—Testimonies, vol. 9, p. 19. IIO 236.4

Olùgbàlà kì yóò pa isé tí a pín. Lójoojúmọ́ àwon òsìsé Olórun gbodò kó ìtumò fífi ara eni jìn pátápátá.—Gospel Workers, p. 113. IIO 236.5