ISE ISIN ONIGBAGBO
Ìwà Rere Àti Ìyìn Onígbàgbó
Àìní ìwà ìbu ìyìn fún òótó àti ìwà àtúnse ti Onígbàgbó láarin àwa tí ń pa ojó Ìsinmi kèéje mó ni ó ń takò wá gégébí ènìyàn tí a sì ti òtító òrò tí a jéwó yìí di òbu tí kò ládùn lénu mó. Isé ìdánilékòó lórí okàn àti ìwà lè máa tè síwájú dé abala tí ó pé. Sùgbón tí àwon tí ó jéwó òtító yìí kò bá tún àwon ànfààní tí wón ní wònyí se láti di ènìyàn Kristi tòótó lékúnréré, won kò ní lè jé ohun èlò olá fún òtító tàbí ohun èlò olá fún Kristi.—Testimonies, vol. 4, pp. 358, 359. IIO 226.1
E ríi dájú pé e mú ìwà rere isé yìí dúró nípa gbígbé ìgbé ayé ìwà àti òrò rere, kí èrù àti gbé gbèdéke isé náà sókè máse bà wá. IIO 226.2
E jé kí a gbé gbogbo àwon ìwà agò àti ìwà rúdurùdu tì ségbè ẹ́ kan, kí a sì gbé gbogbo àmúye ìwà rere láruge. E má se fi àyè gba ìwà òpè òhun agò àti síse ohun gbogbo ní pàjáìrì. E má gba àwon ìwà búburú yìí gégébí ìwà rere nítorí Olor´un kò rí won bé è. E kíyèsára láti máa se enikéni láìnídìí.—Review and Herald, Nov. 25, 1890. IIO 226.3
Àwon ohun àìgbodò máse kan wà tí àwon ènìyàn tí ó ní ìmò Olórun gbodò kó láti se kí won le se àseyorí nínú isé Rè.Wón gbodò jé eni tí ìwà rè dára, tí ó ní ìmò tí kìí se fàwòrajà, àmòtékùn ènìyàn nínú àwò àgùtàn bíkòse eni tí ó ní irú ìwà rere àti ìwà pèlé èyí tí ó ń mú inú ogun òrun dùn, èyí tí gbogbo Onígbàgbó yóò ní tí wón bá jé akópa nínú isé àtòkèwá yìí.—Testimonies, vol. 4, p. 358. IIO 226.4
A ní òtító ńlá àti ìrètí èyí tí ó dára jùlo, àti ìgbàgbó ń lá nínú èyí tí à ń fé se asojú nínú ìwà Rè sí ayé. A kò kàn fé gbé ìwà náà wò gégébí eni tí ó kàn ń la ayé kojá lo lásán tí ó sì ń be ayé nítorí tí a rò wípé a gbàgbó nínú òtító mímó tí ó sòwón yìí, sùgbón à ń fé bá Olórun rìn pèlú ìrèlè kí a sì sé ara wa gégébí omo Olórun Ògá Ògo, àti bí a ti jé ohun èlò àìlágbára tí a sì ń fi owó pàtàkì mú àwon isé ìránsé pàtàkì yìí ju àwon ayé tí ó wà fún ìgbà díè.—Review and Herald, July 26, 1887. IIO 227.1
Àwon òsìsé ajèrè okàn wònyí nílò ìyàsìmímó, ìwà tító, ogbón, agbára, aápon. Kò sí eni tí ó lè ka eni tí ó bá ní àwon àmúye wònyìí sí èniyàn yepere, kàkà béè yóò jé eni tí ó ní ipa rere lórí àwon ènìyàn.—Gospel Workers, p. 111. IIO 227.2
E jé kí a ríi pé a kó gbogbo eni tí ó bá nífè ẹ́ ní ònà tí ó dára jùlo tí a lè gbà fi bá àwon ènìyàn sòrò. Wón gbodò jé eni tí ó ní ìmótótó sùgbón tí kìí se ológe, kí won sì ní ìwà tí àwon ènìyàn kò kórírà. Àní àwon ìwà rere òtító èyí tí àwon ènìyàn fé láarin wa gégébí ènìyàn. Gbogbo eni tí ó bá fé se isé ìjèrè okàn gbodò se àfarawé àwon àmúye wònyìí.—Testimonies, vol. 4, pp. 391, 392. IIO 227.3