ISE ISIN ONIGBAGBO

219/273

Òrò Òlàjú

Òlàjú tòótó àti agbára tí ó wà nínú òrò níí se ní gbogbo ònà pèlú isé Onígbàgbó. Ó ye kí a kó bí a sé ń sòrò ní ònà tí ó wuyì, nípa lílo èdè ní ònà tí rere èyí tí ó dára pèlú òyàyà tí ó sì tó.—Christ’s Object Lessons, p. 336. IIO 223.4

Gbogbo àwon oníwàásù àti olùkó ni ó ye kí won mò wípé isé ìránsé ti ayérayé ni àwon ń fún ènìyàn. Òtító òrò tí a so ni yóò sì dá won lẹ́ọ́ú ní òjó ìdájó. Bí a se ń gbé òrò kalè níwájú àwon ènìyàn ni yóò jé kí ó jé ìtéwógbà tàbí ìkòsílè níwájú won. Nítorí náà e jé kí òrò enu wa ó dùn mó won létí kí ó sì pàrowà fún okàn won tóbéè tí yóò fi ní ìtumò ní okàn won. Ní díèdíè pèlú ònà tí ó yàtò tí ó sì lówò pèlú ìtara kíkan-kíkan èyí tí yóò lè fa pàtàkì isé náà yo ni a gbé òrò wa kalè níwájú won.—Christ’s Object Lessons, p. 336. IIO 224.1

Bí a se ń gbìyànjú láti fa àwon ènìyàn tó kù tí ó wà nínú agbo ìfé Rè, e jé kí òrò enu wa tí ó mó gaara, isé ìsìn tí kò ní ìmò-ti-ara-eni nìkan àti ayò ìwà rere wa jérìí sí agbára oore-òfé Rè.—The Ministry of Healing, p. 156. IIO 224.2

Gbogbo Onígbàgbó ni a pè láti jé kí gbogbo eniyan kó mò nípa òrò Kristi tí kò se é wádìí, nítorí náà e jé kí a ṣóra púpò nípa òrò enu. E jé kí a gbé òrò Olórun kalè ní ònà tí yóò fi ní ìtumò létí àwon olùgbó. Kìí se àgbékalè Olorun nipé kí àwon tí ó ń s o òrò Rè kó jé àjèjì lódò àwon ènìyàn.Kìí ṣe ìfé ẹ Rẹ̀ kí àwon ènìyàn tí ó ń so òrò Rè di yepere.—Christ’s Object Lessons, p. 336. IIO 224.3

E jé kí a kó pèlú sùúrù, inú rere, pèlépèlé àti ònà tí ó ran ni lówó. nígbà tí a bá gbé ìgbé ayé Kristeni tòótó nítorí wọ́n mò pé Kristi tí ó jé Olùbádámòràn won kò fé òrò tó le tàbí òrò búburú. Òrò ọ wọn yóò jé mímó, agbára òrò tí a fifún won jé èbùn pàtàkì tí a yá wọn láti ṣe iṣé tí ó ga tí ó sì jẹ́ mímọ́.—Gospel Workers, p. 97. IIO 224.4