ISE ISIN ONIGBAGBO
Inú Kan
Nígbà tí Kristi so fún àwon omo èyìn pé “E lo ní orúko Mi láti pe àwon ènìyàn sí inú ìjo, àwon tí ó gbàgbó”. Ó gbé e ka iwájú u wọn bí inú kan ṣe jé dandan.Bí íṣeféfé tàbí ṣe kárími bá kéré, púpò ni ipa won fún isé rere yóò jé. Àwon omo èyìn ní láti sòrò láì ní àbùlà gégé bí Jesu ti sòrò.—The Acts of the Apostles, p. 28. IIO 233.3
A lè bá òpò ènìyàn sòrò ní ònà tí kò ní àbùlà àti ìrèlè.Ẹni tí ó ní òye jùlọ,àwọn tí à ń wò láyé gẹ́gẹ́ bí olóye ọkùnrin àti obínrinn, ni à ń sọjí ní òpò ìgbà nípa ọ̀rọ̀ tí kò lábùlà láti enu eni tí ó nífè ẹ́ Olórun, a máa mú àwon ènìyàn tí ó lóye àti èbùn sojí. Òrò tí a ti pèsè tí a ko dáradára mà le ní ipa púpò, sùgbón òrò òtító tí a so tinútinú àti àìníàbùlà láti enu omo Olórun ní agbára láti yí okàn eni tí ó ti jìnà sí Olórun àti ìfé ẹ rè.—Christ’s Object Lessons, p. 232. IIO 233.4