ISE ISIN ONIGBAGBO
Ìse Déédé
Krìstèénì tòótó yóò sisé fún Olórun nínú ìlànà rè, kí se fún ojó tàbí osù kan bíkòse fún gbogbo ojó ayé rè làì fi ti ara rè se é.—Counsels to Teachers, p. 518. IIO 232.1
Olùgbàlà kí eni tirè nínú isé rè. A fùn ní agbára láti fi sisé fún ìran omo ènìyàn. Gbogbo òsán Rè ló fi sisé tí ó sì fi gbogbo alé gbàdúrà, kí ó lè dojúko òtá àti ìmò búburú rè, ohun isé rè láti fi gba omo ènìyàn là. Eni tí ó bá fé Olórun kì ígbé gégé bí i wákàtí méjo ni a fi ń sise lé isé rè. Á fi gbogbo wákàtí rè sisé láì se ìsáǹsá rárá. Ó ń se ohun rere nígbàkuùgbà, ó ń rí ànfààní láti se isé fún Olórun. Ó ní àmuye tí ó ń fanimóra ní ìgbà gbogbo.—Testimonies, vol. 9, p. 45. IIO 232.2
Eni tí ó bá fi ìwà àìtó tàbí àìbìkítà jé kí isé Olórun denukolè tàbí eni tí ó dí àwon òsìsé rè lówó, fi owó ara rè fàbàwón tí ó sòro láti wè kúrò sórí ara rè, béè ni ó sì gbé ìdènà ti ipa ìwúlò rè ní ojó iwájú.—Prophets and Kings, p. 659. IIO 232.3
Jesu wípé “Gbé àjàgà mi rù”. Àjàgà yìí ni irin isé. À ń gbé àjàgà sórí màálù láti jé kí ó sisé, àjàgà yìí wúlò púpò láti jé kí won ó sisé dáadáa. Pèlú àjàgà yìí, Krístì ń kó wa pé a pè wá láti se isé ìsìn ní gbogbo ojó ayé wa. Ká gba àjàgà rè sórí, kí a lè bá jé a-lá-bàá-jo-ṣiṣé-pò.—The Desire of Ages, p. 329. IIO 232.4