ISE ISIN ONIGBAGBO

178/273

ORÍ KẸTÀDÍNLÓGÚN Ìràńlọ́wọ́ ọ Ti Àwọn Onígbàgbọ́

Títọ Ipa Ọ̀run Lẹ́hìn

Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ènìyàn ni wọ́n rò wípé anfààní ńlá ni yóò jẹ́ fún wọn láti ṣe àbẹ̀wò sí ibi ìgbé ayé Jésù nígbà tí Ó wà lááyé, láti rìn ní ọ̀nà tí ó gbà, àti láti tọ ipa ọ̀nà tí ó nífẹ̀ẹ́ láti kọ́. (The Desire of Ages, pp. 86, 87). IIO 186.1