ISE ISIN ONIGBAGBO

73/273

Àwọn Ẹ̀kọ́ Láti Inú Ètò Tí ó Péye.

Ọlọ́run rò pé a gbọdọ̀ kọ́ nípa ètò àti ìkójọ láti ara ètò pípé tí Ó gbé kalẹ̀ nígbà ayé e Mósè, fún ànfààní àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.- Testimonies,vol.1, p.653. IIO 73.3