ISE ISIN ONIGBAGBO

267/273

ORÍ KẸTÀDÍNLÓGBÒN ÈRÈ — ISÉ

Àìníye

Kìí se ohun asán láti sin Olórun. Èrè àìníye wà fún àwon tí ó bá fi ayé won sílè láti sisé fún.-Testimonies, Vol. 4, p. 107. IIO 266.1

Gbogbo ipá tí a sà nínú isé ẹ Rè ni a yóò gba èrè rè nínú ògo olá ń lá a Rè.-The Desire of Ages, p. 249. IIO 266.2

Èrè wà bí a ti ń ṣiṣẹ́ pèlú Olórun ni pé a yóò ní ànfààní láti bá a sisé nínú ayé tó ń bò.-Christ’s Object Lesson, p 361. IIO 266.3